Download organized and Detailed Yoruba Language Lesson Notes for JSS3/Basic 9 First term in PDF or Document – Edudelight Store
Junior Secondary School 3 (JSS3) Yoruba Language Scheme of work with Lesson notes Content
| OSE | AKORI EKO |
| 1 | EDE – Atunyewo fonoloji Ede Yoruba iparoje ati isunki
ASA – Isinku ni ile Yoruba LITIRESO – Awon Ewi Alohun ti o je mo esin abalaye iyere: ifa, Sango pipe |
| 2 | EDE – Aroko Alalaye
ASA – Ogun pinpin LITIRESO – Awon ewi alohun ti o je mo esin abalaye – yala, iwi egungun, oya pipe |
| 3 | EDE – Atunyewo awon apola ninu gbolohun ede Yoruba. Apola oruko ati Apola ise
ASA – Asa ati suyo ninu awon ewi atohun ti o fem o esin abalaye ijale, iwi egungun, Oya pipe, Sango pipe. LITIRESO – Kika iwe litireso apileke ti Yoruba |
| 4 | EDE – Atunyewo awon eye gbolohun ti o wa ninu ede Yoruba
ASA – Atunyewo awon ere idaraye ile Yoruba LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan |
| 5 | EDE – Gbolohun ibeere – awon iwure ti a fi n se ibeere da, nko, nje, taki
ASA – Atunyewo asa iran a enilowo, owe, aaro, obese, esuse, ajo LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan |
| 6 | EDE – Atunyewo ami ohun ati silebu
ASA – Atunyewo asa iran ra eni lowo owe, aaro, obese, esusu, ajo LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan |
| 7 | EDE – Atunyewo lori ibasepo laarin awe gbolohun ede Yoruba
ASA – Awon orisa ile Yoruba obalale LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan |
| 8 | EDE – Atunyewo orisirisii eya awe gbolohun
ASA – Awon oris ile Yoruba – Ogun LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan |
| 9. | Akaye: Kika Akaye lori itan aroso |
| 10 | Apeko: Awon gbolohun keekee Yoruba |
| 11 & 12 | Atunyewo ise saa yii |
| 13 | Idanwo ase kagba fun saa yii |
JSS3 First Term Yoruba Language Lesson Note – Edudelight Store

Reviews
There are no reviews yet.