Download Comprehensive Junior Secondary School Yoruba Language Lesson notes Basic 9 /JSS3 2nd term in PDF, DOC – Edudelight Store
Basic 9 Yoruba Language Scheme of work with Lesson notes Content for second term
| OSE | AKORI EKO |
| 1 | EDE – Ihun orisirisi awe gbolohun po lati di odidi gbolohun
ASA – Awon asa to suyo lati inu awon ewi alohun LITIRESO – Kika iwe literaso apileko ti ijoba yan |
| 2 | EDE – Atunyewo leta kiko (aigbefe)
ASA – Awon oriisa ati eewo to suyo ninu litireso alohun ti a n fi oro inu won daa mo LITIRESO – Ifaara lori litireso alohun |
| 3 | EDE – Iyato ti o wa laarin apola ati awe gbolohun Yoruba
ASA – Itan isedale agbala aye LITIRESO – Kika iwe litireso apileke ti ijoba yan |
| 4 | EDE – Aroka alalaye
ASA – Owe ile Yoruba LITIRESO – Oriki orile elerin, olokun, esin, onikoyi, olofa abbl. |
| 5 | EDE – Gbolohun Onibo
ASA – Awon akanlo oro inu ede ati awujo Yoruba LITIRESO – Kika iwe apileko ti ijoba yan |
| 6 | EDE – Akaye oloro wuuru / geere
ASA – Awon orisa to suyo ninu litireso LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan |
| 7 | EDE – Akaye II (Ewi)
ASA – Awon imole / orisa to suyo ninu litireso LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan |
| 8 | EDE – Atunyewo awon oro eyan
ASA – Igbese igbeyawo ni ile Yoruba LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan |
| 9. | EDE – Atunyewo awon oro aponle
ASA – Ikomojade ni ile Yoruba LITIRESO – Kika iwe apileko ti ijoba yan |
| 10 | Atunyewo ise lori ise saa yii lori ede, asa ati litireso |
| 11 | Idanwo ipari saa keji |
| 12 | Ifi – owo si iwe idanwo |
Basic 9 Second Term Yoruba Language Lesson Note – Edudelight Store

Reviews
There are no reviews yet.