Sale!

Yoruba Language Lesson Notes for SSS3 First Term

Original price was: ₦1,500.00.Current price is: ₦500.00.

  • PDF
  • Document (Editable)
  • Comprehensive
  • Printable
  • NERDC Curriculum Compliant
  • Effective and Efficient
  •  Well Organised
  • Well Detailed
  • Soft Copy
  • Reference Available
  • Evaluation (Questions) Available

Download well organized and Detailed Yoruba Language Lesson Notes for SSS3 First term in PDF or Document format – Edudelight Store

Senior Secondary School 3 First term Yoruba Language Scheme of work with lesson notes content

 

OSE AKORI EKO
1 EDE – Itesiwaju eko lori oro ise; Alaye lori orisii ati ilo re ninu gbolohun

ASA – Afiwe asa Isinku abinibi ati eto sinku ode oni. Ayipada to ti de ba Asa isinku abinibi tabi atohunrinwa

LITIRESO – Agbeyewo iwe ti Ajo WAEC/NECO yan. Onkowe, itan ni soki ati awon amuye miiran

2 EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. Gbolohun eleyo oro ise, gbolohun olopo oro-ise, sise akojopo gbolohun eleyo oro-ise.

ASA – Eto ogunjije. Awon iran/orile ti o maa n jagun ni ile Yoruba laye atijo. Eto aabo ilu ati ipati awon obinrin n ko ninu eto ogun

LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan

3 EDE – Itesiwaju lori ihun oro

Dida oro oruko ti asede mo yato si eyi ti a ko seda

Itupale oro oruko eniyan, sise akojopo oro oruko

ASA – Itesiwaju eko lori Egbe Awo

Orisirisii egbe Awo ti o wa nile Yoruba

Alaye kiku lori ipa ti awon egbe wonyii n ko ninu eto oselu

LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan

4 EDE – Iba Isele (Aseranwo oro-ise)

i.                    Orisii iba isele to wa Asetan, Aterere, Aisetan abbl

ii.                  Awon wunreni ti o toka iba isele ninu gbolohun

ASA – Itesiwaju eko nipa igbagbo ati ero Yoruba nipa oso ati aje. Ero ati igbagbo awon eya miiran ni orile ede Naijiiria ati orile ede miiran nipa oso ati aje

LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan

5 EDE – Itesiwaju lori Oro Agbaso

Yiyo oro enu oloro si oro agbaso, fifi eti si sise, kika ati jijabo iroyin ipade

Yiya afo agba oro si afo-asafo

ASA – Itesiwaju lori Eko ile ati imototo itoju ara, bi a se nkini, oro siso, onje jije ati awo fifo

LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan

6 EDE – Itesiwaju lori oro aroko oniroyin, ijiroro kikun lori awon ori oro to je mo aroko oniroyin. Kiko ilapa ero

ASA – Itesiwaju eko lori ojuse eni ni awujo pataki ojuse eni ninu ile, laarin ebi, egbe, adugbo, abbl

LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan

7 EDE – Iyato to wa laarin Oro Aponle ati Apola Aponle, alaye kikun. Oro Aponle ati Apola Aponle, titoka si ilo oro aponle ninu gbolohun, fifa oro aponle ati apola aponle yo ninu gbolohun tabi ipinro, sise alaye ise okookan won ninu gbolohun. Alopo mejeeji ninu gbolohun

ASA – Itesiwaju lori oran dida ati ijiya ti o to ipa ti awon agbefoba ati agbonfinro n ko ninu sise eto idajo fun arufin ati odaran, orisii eto idajo ati oan ti a o gba fi iya je odaran laye atijo ati ode oni

LITIRESO – Ayewo finifini lori awon Asayn itandowe. Itandowe siso, itandowe kookan ni oloro geere titoba si oew ati asa to suyo ninu itan kookan, isowolo ede ninu itan to di owe kookan.

8 EDE – itesiwaju ninu aayan ogbufo. Ogbon ti a n ta fun aayan ogbufo lati ede geesi si ojulowo ede Yoruba. Fifoye itumo ayoka oloro geere to ta koko jut i ateyinwa lo lati inu ede geesi si ojulowo Yoruba ajumolo

ASA – Itesiwaju nipa igbagbo awon Yoruba si aseyin waye ati abami eda

LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan

9. EDE – Itesiwaju Akaye Ayoka (orisirisi, agbeyewo orisirisi, akaye bii oloro geere, ewi, ere onitan, ati orisii ayoka danra wo

ASA – Itesiwaju lori eewo. Awon eewo ti aisan mu wa akojopo aisan ati eewo ti alaisan kookan ko gbodo deja, anfaani awon eewo fun awon alaisan

LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan

10 EDE – Atunyewo awon isori oro-oruko, oro aropo oruko, oro ise, sise itupale gbolohun kekere si isori oro

ASA – Itesiwaju lori oruko ile Yoruba, oruko Amutorunwa, oruko abiso ati oriki inagije

LITIRESO –  Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan

11 Atunyewo eko lori ise saa yii ninu ede, asa ati litireso
12 Akanse idanwo lori eko, ede, asa ati litireso

 

SS2 First Term Yoruba Language Lesson Note – Edudelight Store

Choose Download Format

Microsoft Word Document/WPS Office, PDF

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “Yoruba Language Lesson Notes for SSS3 First Term”

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Billing details

Additional information

Your order

Product
Quantity
Total
Cart Subtotal ₦0.00
Order Total ₦0.00
  • Kindly, make your payment directly into our bank account. Please use your Order Number as the payment reference. Your Order will be sent to you through WhatsApp, Telegram or Email immediately after confirmation of Payment.

kindly click on "Add to Order or Cart" to order now!
If you have added this product to cart, kindly click on "Place order" to order now! Our privacy policy.